Eyinju

Song

Eyinju

Nifemi David

Nifemi David Eyinju Mp3 Download

Nigeria Gospel singer Nifemi David, come up with her masterpiece tagged “Eyinju” the song is captivating and mind-blowing. The sound is amazing.

Nifemi David Eyinju Lyrics

K'atọ to dọmọ lo tí mọ mí
O pe mi L'eyinju uuu
Kí n to dọmọ lo tí mọ ohun maa da o
Ogo fún ẹni to dami
K'atọ to dọmọ lo tí mọ mí
O pe mi L'eyinju uuu
Kí n to dọmọ lo tí mọ ohun maa da o
Ogo fún ẹni to dami
Eweko kò ni Jabo
Kọ sẹhin Olodumare
Òhun ti mo máà dà ti mo n da lọwọ
O ti wa ninu eto óo bàbá ooo
Eleda tó dá mi
O ma ṣe eee ooo
K'ẹjẹ to dọmọ lo tí mọ mi
O pe mi L'eyinju uuu
Kí n to dọmọ lo tí mọ ohun maa da o
Ogo fún ẹni to dami
Eto Ọlọrun ni mi
Ẹda ayé o le pe mi lasiṣe
Ninu eto Ọlọrun ni mo wa
Eyi ló fí f'ẹtọ fún mí
Ẹtọ èyí l'ogo to ṣe mi yatọ
A o ko dami gan lasan
O ni a dami ni ìrì oun
And he took it personal
O pe mi ní ògo, ọla, ire
Ọrọ ibukun rẹpẹtẹ
E yíì ṣa l'ẹri ifẹ Oluwa simiii pẹ
K'atọ to dọmọ lo tí mọ mí
O pe mi L'eyinju uuu
Kí n to dọmọ lo tí mọ ohun maa da o
Ogo fún ẹni to dami
K'ẹda ayé máa sáré òhun to wá leto
Mi o ni duro sùgbón ma kanju
Ma dẹ sáré asa ju laye
Ẹlẹtọ ni iṣẹda kò ni rẹ' ọ jẹ
O wa ninu eto o
Ẹtọ a tẹ ọ lọwọ
O ti mọmi ooo ka to dami sinu
Kí n to tinu Jade lo tí sọ mi di mímọ
Aya mi s'ọtọ ọọ
Ayé mi n bọla fún ìdá ti o lasiṣe
Peki ni ire n ṣere lọdọ emi
Eyinju baba
O f'ogo fún ùn
O f'ola fun
O f'ogo fún ùn
O f'ola fun
K'ẹjẹ to dọmọ lo tí mọ mi
O pe mi L'eyinju uuu
Kí n to dọmọ lo tí mọ ohun maa da o
Ogo fún ẹni to dami

About Eyinju

Released 2024
Duration 04:20
Artist(s) Nifemi David
Genre Gospel
Songwriter(s) Nifemi David
To Download: Download usually starts in few seconds.
If ads pops up, close the ads tab and return to this page/tab the download should start after you click the download button!!.



Frequently Asked Questions

Which site can I download Eyinju by Nifemi David?

The best website to download Nifemi David Eyinju Mp3 Download is 36extra.com.


Where can I download Eyinju by Nifemi David?

You can download Eyinju by Nifemi David here on 36extra.com.


How do I download Eyinju by Nifemi David?

You can download ">Nifemi David Eyinju Mp3 Download in 4 easy steps.

  1. Go to https://36extra.com
  2. Search for the song and click on it
  3. Scroll to the download link and click on it to go to the download page
  4. Click on the download button

Who sang Eyinju?

The music Eyinju was sung by Nifemi David


Comment Box is loading comments...